Smiley face

Basketmouth Alawada Ra Oko Ti Owo Re To N26M

 
Edumare fi ere si ise wa. Ti Oluwa oba ba ti fere si ise ẹda bi igba eniyan lọgbọn lori nii da loju omo adamo. Basketmouth Alawada ni iroyin kan wa nipa re wi pe o ra oko tuntun 2015 Lexus 570 SUV ti owo re to N26M.

Emi re yo lo, oba oke o se tawon ti okan won on pongbẹ ohun rere bi eyi.




Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment