Olori Ijo Latter Rain Assembly, Pasito Tunde Bakere ti jeri wi pe oun gbagbọ ninu Muhammadu Buhari sugbon awon eniyan to yika jẹ awon eniyan ti won ko see jẹri rara nitori wi pe won ko see gbara le.
Bi o tile je wi pe Alufa Tunde Bakarfe ko daruko awon eniyan to yi Buhari ka eleyii to gbagbo wi pe won ko see gbarale, sugbon gbogbo wa la mo wi pe awon eniyan bi Bola Tinubu lo n sọrọ ọ ba. Alufa Tunde Bakare ati Bola Tinubu ko jọ fi igba kankan wa lori ọwọ kan naa lati ibẹrẹ pẹpe.“Yes I trust Buhari and this is because I have worked closely with him but I doubt his environment. The Peoples Democratic Party and the All Progressives Congress, which one is really clean? Only God can give us true leaders,” oro enu Bakare
0 comments:
Post a Comment