Aworan ohun isere awon omode yii ni enikan fi ranse si mi lori ero BB mi pelu akole to fi le to n so wi pe: "Kini aworan naa lojo ninu okan mi?"
E mi o mo ohun to jo sugbon o da mi loju wi pe eyin o le so fun mi ki n le resi dapada.
E gbo, kini aworan naa jo?
Nigba ti e n pinnu lati fun mi lesi. E je ka wo die ninu aworan awon onise tiata ile Nigeria.
E ku faaji opin ose

E joo, e wo ni ti anti isale yii? Se awon naa n se ise tiata ni abi oge ni ka pe ti won. O ga ju!
0 comments:
Post a Comment