Smiley face

E WA Wo Omoge Ti N Ri Ihoho Kiri Ilu New York

Erica Simone, to je onise-ọna ayaworan lo ti bẹrẹ si ni se akojopo awon foto rẹ eleyii to n ya ni ihoho kiri ilu New York bayii. Won ni obirin naa fẹ gbe iwe kan jade eleyii ti akole rẹ yoo jẹ "Nue York: Self-Portraits of a Bare Urban Citizen". Ninu iwe naa lo ti fe lo awon aworan ti n ya kiri igboro yii.

Omobirin naa ti so ero re nipa ihoho ara re ti n gbe kiri igboro:

"The point is not to be nude for shock value. I am simply an artist looking to humorously poke at some interesting thoughts about society and question who we are and embody as human beings inhabiting this home we call Earth. It’s now up to you to answer or raise these questions, as you like."

"Naked is who we are and who we come into the world as. 'Nothing Fits Like You'‬ is a campaign about being comfortable with who you are as a person, with your body, your mind and your role in society. It's about being free from the confinements of societal expectations and the media's projections."





Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment