Eni ba yo tan ti n wa bekunbekun kiri lọrọ awon ọlọmọge ti won gbe ike sinu idi ki idi won le ranju bọnbọn labẹ aso.
Omoge kan ni ilu Los Angeles to gbe rọba omi sinu idi, ni rọba fọ nibi oun ati alẹ rẹ ti n yata. Gẹgẹ bi a se gbọ, ọna eyin ni maanu naa gba wọle nibi o ti n kona fun un kikankikan eleyii to pada jasi ohun to sokunfa bi ọra omi ti mbe ninu di rẹ se fọ pau.
Igba ti ọra fọ, omi kẹmika ti won rọ sinu ọra naa bẹẹ sini jo sinu idi rẹ. Eleyii to pada yii awọ idi re pada, ti gbogbo rẹ si n ja butẹbutẹ bi burẹdi
E tun le ka iru iroyin to fara pẹ eleyii NIBI
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment