Smiley face

E Wa Wo Oloyun Ti N Wa Kẹkẹ Maruwa Ni Ilu Ẹko

Nibayii, mo ti wa gba wi pe ko si ohun ti okunrin se ti obirin ko le se. Eleyii to je ohun iwuri lopolopo lati ri idagbasoke ati anfaani awon obirin se n gberu sii lawujo wa. Sugbon sa, opolopo ise ti awon obirin n se ni akoko yii kii se wi pe won je akikanju lo mu won maa se awon ise okunrin, bikose airikan-sekan ati òsì to ti ba ilẹ wa damajẹmu latari awon asaaju wa ti won ko bikita fun awon ara ilu.

Ni o ya yin lenu lati mo wi pe Arabirin Olayinka Adeyemo kawe gboye jade ni Ifafiti, sabuke re si dara pupo. Sugbon airisẹ se lo sun de bi ẹni ti n wa Kẹkẹ Maruwa kiri igboro. Arabirin naa ti loyun sikun bayii, sibesibe, o si n ba ise re lo ni rebutu ni. Alaye lati enu arabirin naa ni yii:


    Please madam, how did you get into this keke (tricycle) business?
    “My brother, I’m a graduate, but rather than stay idle coupled with the responsibility of taking care of my young family, a friend of mine encouraged me to take-up this business. First, I got this tricycle through a hire-purchase arrangement from this friend, but now it’s mine because I’m done with paying up the cost of the tricycle.”


    How does it feel operating in a man’s world?
     I don’t feel any different. I’m working and the men are working too. The difference is that I get more considerations from bus-stop touts who milk us of our earnings because I’m a woman, and when they see my protruding tummy, they just let me be.


    And your condition?
  “I’m only pregnant. I’m not sick. Yes, I’m often tired, but this work is all I have to contribute to my family economy and meet my personal needs”. And your husband? “He‘s been very supportive and my children and family members know this is what I do for a living and they respect me for that”.


    Are making a lot of money?
    “I wouldn’t say a lot of money, but it’s better than staying idle, and waiting for my husband to do everything for me.”
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment