Ise abiyamo aye lori idile won ko kere, se lati ibi itoju omo debi ile ni ka so, oun naa ni o tun se itoju oko re bi igba eniyan toju omo-ikoko. Se o tun wa ye ki iru awon obirin bayii tun maa jeya tabi ki awon okunrin maa fi oju won rara? Lonii mo se iranti awon abiyamo aye, adura mi si mi wi pe owo to se egusi naa ni o pade je.
Kini iriri yin nipa iya ti awon okunrin fi n je awon obirin laye ode onii?
0 comments:
Post a Comment