Smiley face

Terry G se Afihan Iya To Bi Lọmọ : Iya Naa Dabi ỌmỌge Ogun Odun

Terry G, okan ninu awon olorin takasufe ilu Nigeria, eni ti awon kan tun mo si Apako Master se afiham mọda rẹ fun gbogbo aye lonii. Awon kan so wi pe iya naa ko tile dabi iya re rara, a fi bi anti re lo jo. Awon kan ni Baba Terry G lo ye ka yin lawo. Nitori ohun gbogbo wa lọwọ lilo. Ti okunrin mii ba lo Obirin bayii, eniyan a fẹ ẹ le sintọ siru obirin bee lara.

Fun idi yii, ti adelebọ to ba ti lo bi ọgbọn odun ni ile ọkọ to si tun dabi adelebọ, ọkọ rẹ lo ye ka yin lawo.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment