Smiley face

Awon Wo Lo Wa Ninu Foto Yii?

Awon Yoruba bo, won ni ori taa fi sewe kii kuro lorun eni taaba dagba lagba. Ati wi pe bi omode o ku, dandan ni ko dagba lagba. Owe awon Yoruba naa lo si so wi pe, won ko ni bimo niso sokoto ko wa ya kijipa, sebi eni bini baayii laajo.

O da naa, nje n pade sori ibeere akole iroyin yii.

Awon Wo Lo Wa Ninu Foto Yii?

Aponle: mo ri foto yii lati owo Kola Olootu
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment