Lojo iku eerin, orisiirisii obe laa ri. Bi ojumo se n mo, ni orisiirisii aso oge tun-un gba igboro kan Se ka gba wi pe okan lara awon aso oge igbalode ni yii abi akisa lasan? Emi o le so, sugbon o damiloju wi pe idahun to peye wa lowo yin.
E ku faaji opin ose!
0 comments:
Post a Comment