![](https://blogger.googleusercontent.com/img/b/R29vZ2xl/AVvXsEgNcx9Fkbsfhq86Ay9d9aG-Kjb-awbOqNvfv69WS-iStTAtmhpv9hVZ8ha6E2Mqgj7mQmMrRIlPIjbjPdYTUtoHT0Qsan1kI8YkvCEJzG6Xkzx4SgAoGeqGgexNtydcqcWfVEEfWZgGNzk/s1600/0.jpg)
Funke Akindele tun ti pada sigboro ilu Eko lati maa beere si ni se ipolowo ati ipolongo ose OMO eleyii to ti n sebo seyin. Sugbon ka maa paro, Jenifa ti sanra sii. Ereke re ati igbaya re tun ti jade sita ju ti tele lo. O n dan lawo, erin enu re si yato si teni to n tiraka a ti fehin lo. Alaafia ati ifokanbale lo ju laye, bi eda ba ti ni ifokanbale ati alaafia, gbogbo ohun ti o to ni o bo wa seku.
Ju gbogbo re, E maa reti Jenifa ni adugbo yin laipe yii.
0 comments:
Post a Comment