Kii se Foto Morufa ni yii |
Iriri aye ki i ti ni titi ko ti ni pa,
ogbon ni fi i n ko ni; awon agba lo so bee. Morufa Yekeeni ti fi leta kan sowo
siwa laipe yii eleyii to ni ka ba oun gbe sita ki awon eniyan fi le kogbon. Ninu
leta naa ni Morufa ti Salaye irinajo re si ilu Eko lati ilu Ibadan ni ileto kan
ti n je Amuloko. Ise owo ni won ni Morufa yo ko to ba de ilu Eko, sugbon nigba
to debe, ise aje lo n muu se lodo anti re to mu lo si ilu Eko. Morufa so sinu
leta re to ko gbeyin wi pe ohun kabamo wi pe ohun wa si ilu Eko, nje iru abamo
wo lo de ba Morufa ni ilu Eko aromi-sa-legbelegbe? Eleyii ni Omobirin naa
seleri wi pe ohun yoo salaye fun wa ninu leta re tuntun to n bo lona. Leta
tuntun naa ti wa de bayii. Sugbon fun anfaani eyin ti e ko ri leta Morufa to
koko fi ranse ka, e le ka leta naa [NIBI]
ki itesiwaju alaye re le ye yin pupo.
Sii Olootu,
Siwaju naa, mo tun fe dupe lowo
Olayemi Oniroyin gege bi won se gbe leta mi akoko jade. Inu mi dun gidigidi
gan-an pelu bi mo se ri leta mi lori ayelujara.
Edumare yoo ran gbogbo wa lowo.
Iresi, ewa, dodo, isu,
buredi,macaroni, ati asaro je orisi awon ounje ti anti mi maa pate loja Oshodi
nibi ti a ti n ta ounje. Se e o gbagbe wi pe emi kan naa ni mo ma lo n gbe
ounje osan fun oko anti mi ni iso re. Nigba mii ti mo ba gbe ounje lo fun oko
anti mi, o le ni ounje naa ko wu oun je rara, a si ran mi ni amala dudu pelu
abula. Ounje ti mo ba gbe wa ti ko ba ti je, iru ounje bee yoo si je ajegbadun
fun omose re. Sugbon eleyii kii saba maa n waye lopo igba.
Lojo kan ni mo gbe ounje lo fun oko
anti mi niso nibi to ti n ta eran, o so fun mi wi pe ara oun ko ya rara, ati wi
pe o fe da bi eni wi pe oun fe ni iba die. Ibi to joko si ni mo ba a. Omose re
n pe awon ero ti won koja lo wi pe ki won wa ra eran. Ti kositoma ba duro ni
oko anti mi o dide. O so fun mi wi pe oun ti ra ogun iba kan ti oun fe lo ti
oun ba jeun tan. Sugbon o seese ki ogun naa kun oun loorun nikete ti oun ba gbe
ogun iba naa lura tan. Fun idi eyi, ile ni yoo wu oun lati jeun, ki oun lo ogun
ki oun si sun die ki oun to tun pada siso. O ni ki n gbe ounje lo sile pe oun o
ba mi. O ku ti nibi ti a maa n fi kokoro ile pamo si. Abe eni inuse to wa lenu
ona lo wa, ti a ba ti fe jade, ibe ni a n fi pamo si. Bi mo se dele wi pe ki n
bere mu kokoro naa ni oko anti mi ti de eyin mi, a jo wole. Mo si bere si ni se
aajo re.
Emi: E pele sir.
Oko Anti Mi: O se.
Emi: Sugbon ko si seyin bayii lana
ati laaro yii ke to jade nile. (Awa mejeeji jijo wole)
Oko anti mi: (O lora die ko to soro.
O n sebi eni ara n ni) Nnn… ko se mi bee. Sugbon mo kan sakiye wi pe ara n ro
mi die nigba mo ji laaro yii. Gbogbo ero mi si ni wi pe ara mi ko nipe gbonnu
ti mo ba ti jade. (Mo ti sare lo mu sibi, ounje re si ti wa lori tebu ni iwaju
re ni palo).
Emi: E pele. Wahala moji-moji jade
gan-an kii se keremi. A maa da nnkan si eniyan lara. (Mo ti fi sibi segbe ounje
re sugbon ko nawo mu u. O n wo taanu-taanu ju bi mo ti ba lo nigba to wa loja)
Se iya Kadija si ti mo wi pe ara yin o ya? (Anti mi lo n je iya Khadija). Ti n
ba doja n wi fun won. E sira jeun yin ke le loogun, kee si simi die.
Oko Anti Mi: Ba n te beedi inu ile un
ki n le feyin lele leyin ti n ba setan.
Emi: Ko buru.
Mo wo inu Yara lo la ti lo te beedi.
Mo ko eyin si ona oju ona abawo sinu yara. Ibi ti mo bere si ti mo ti n te
beedi, mo sakiye wi pe eniyan kan yo wole si mi leyin. Mo gbe ori soke, mo boju
weyin. Eniyan dudu ni mo ri, eni naa ga niwo ese bata mefa, aya re nipon bi
igbaaya awon onikootu dudu ti won maa n sare tele moto gomina, bee isan apa re dabi
ori omo odo ti won fin gun yan.
Ihoho goloto naa ni eni naa wa, “opa ase” dudu
ti eni naa so mo idi re gun gboona bi omorogun ti won fi n roka, bee lo ki sara
bi ese maalu. Opa naa wa n mi ori legbelegbe bi alagba to wa legbe ogiri ile.
Aya mi ja, mo boju wo eni naa loju, o di oko anti mi. Mi o tile mo ohun ti mo
le se ni akoko naa, gbogbo opolo ori mi tifo lo. N se ni mo kunle ti mo si bere
si ni bee wi pe ko dakun. Ko dami lohun, o ti mi lu beedi, bi mo se fe gbiyanju
ati pariwo lo ri aso bomi lemu.
Mo gbiyanju agbara mi lati jajabo kuro lowo re,
sugbon iro ni mo pa. Agbara re ju temi lo. Aso kaba pupa ni mo wo ti o lapa, o
ti si mi laso soke, bee lo fi owo fa pata idi mi si egbe kan lai bo kuro. Ope
die ko to ri oju ona abawo le, sugbon nigba to ya, mo fura wi pe nnkan ti wole
si mi lara. Igba yii, mi o wule janpata mo. Sugbon mo n sukun, omi si n jade loju mi. Oko anti mi o dawo duro, gbogbo egun to ni lo fi n han. Gbogbo bo ti to
lo se n wole si mi lara. Mo n gbin sinu, sugbon ohun mi goke.
Kilo sele leyin ise owo oko anti mi?
Nje anti mi gbo si tabi ko gbo?
Ki lo sele si emi gan-an fun ra mi?
Maa tun maa fi leta mi sowo laipe fun
kika. E se
Emi ni ti yin ni tooto,
Morufa Yekeeni
0 comments:
Post a Comment