Sii Olayemi Oniroyin Agbaye Leta eleekerinla (14) mi ni yii, eleyii ni maa si fi kadi itan igbesi aye mi ti mo ti n ba a bo fun igba...
Read More
Home / Morufa Eko
Showing posts with label Morufa Eko. Show all posts
Showing posts with label Morufa Eko. Show all posts
Morufa Eko 13: Asiri Oko Anti Mi Tu Sowo Awon Olopaa
E ku deede iwoyii eyin ololufe wa. E mi Morufa naa ni mo tun un ki yin. E ku ifomoniyanse. Se e o gbagbe ibi ti mo ba alaye mi de...
Read More
Morufa Eko 12: Awon Olopaa Lo Gbe Santana Oko Afesona Mi
Sii Olayemi Oniroyin, Morufa Eko tun ti de o. E ku amojuba mi. Itan igbe aye mi ti mo ti n baa bo lenu bi ojo bi melo kan dabi en...
Read More
Morufa Eko 11: Gbogbo Ara Ile N Wa Mi, Won O Mo Ibi Ti Mo Wa
Sii Olayemi Oniroyin, Mo tun ki yin ku asiko yii eyin ololufe wa. Awon Yoruba ni ti ina ko ba tan laso eje kii tan leekanna. Se ...
Read More
Morufa Eko 10: Awon Obi Mi Lo Fa Ibanuje Sinu Aye Mi
Sii Olayemi Oniroyin, Mo koko fe dupe lowo gbogbo eyin ololufe Olayemi Oniroyin ti e n ba mi ka awon leta mi ti won ba mi te jade fun k...
Read More
Morufa Eko 9: Oko Anti Mi Fi Emi Ati Oyun Inu Mi Se Ogun Owo
Sii Olayemi Oniroyin, Mo ki eyin oluka itan igbesi aye mi fun aduroti yin ati bi e se n ba mi fi okan baa awon alaye naa bo. Leta eleek...
Read More
Morufa Eko 8: Oko Anti Mi Mu Mi Lo Si Ile Babalawo; Ohun Oju Mi Ri Enu O Le Royin Tan
Sii Olayemi Oniroyin, Mo ti ba alaye mi debi ti mo so wi pe mo ti loyun fun oko anti mi. Oko anti mi si ti se ileri lati ba mi se ...
Read More
Morufa Eko 7: Mo Ti Ka ABiDi Mi Debi GBi: Mo Ti Lo Loyun Fun Oko Anti Mi
Sii Olayemi Oniroyin, Awon Yoruba nibi taa roko ti si, ibe naa laa fabo si . Emi gan-an mo wi pe o pe mi ki n to pada wa, sugbon o da...
Read More
Morufa Eko 6: Oko Anti Mi Wa Ka Mi Mo Yara Mi Laago Kan Oru Lojo Ti Ko Si Anti Mi Nile
Morufa Eko ti fi leta eleekafa re ranse, eyi si dun mo wa ninu pupo. Fun anfaani eyin ti e ko mo ibi ti a ba de ati eyin ti ko mo ibi ti...
Read More
Itan Igbesi Aye Morufa Eko: Ibi Ti Morufa Ba Itan Re De Ni Yii
E ku deede iwoyii eyin ololufe wa, gege bee ti mo wi pe o ti to nnkan bi leta marun-un ti Morufa eko ti fi sowo si wa. Sugbon awon kan s...
Read More
Morufa Eko 5: Ore Mi Ni Ki N Maa Fe Oko Anti Mi Sugbon Emi Fe Fun Ni Majele Je Ni
Awon Yoruba nibi taa roko ti si, ibe naa laa fabo si. Morufa Eko ti pada gbe itan igbesi aye re nibi to ba de ninu leta to ko koja . Let...
Read More
Morufa Eko 4: Mo Ti Ra Majele Ti Mo Fe Fi Pa Oko Anti Mi
Ohun akoko to ko koko wa si mi lokan ni majele. Boya ki n fi majele si inu onje re. Sebi iku ni ere ese. Ika to ba se loba n ge. Ti eera...
Read More
Morufa Eko 3: Igbin Oko Anti Mi Ti Fenu Kanyo, O Di Dandan Ko Ku
E ku deede asiko yii gbogbo dukaduaka. Mo si fe fi asiko yii ki gbogbo musulumi aye wi pe won ku awe Ramanda tuntun to wole de. Emi wa...
Read More
Morufa Eko 2: Oko Anti Mi Fa Idi Mi Ya Perepere
Kii se Foto Morufa ni yii Iriri aye ki i ti ni titi ko ti ni pa, ogbon ni fi i n ko ni; awon agba lo so bee. Morufa Yekeeni ti fi l...
Read More
Morufa Eko 1: "Mo Kabamo Wi Pe Mo Wa Si Ilu Eko" - Morufa
Oshodi Sii Olootu, Olayemi Oniroyin, mo ki yin pupo fun bi e se n gbe ede Yoruba laruge nipase awon iroyin yin. Omo ilu Ibadan ni mi,...
Read More
Subscribe to:
Posts
(
Atom
)