Smiley face

Itan Igbesi Aye Morufa Eko: Ibi Ti Morufa Ba Itan Re De Ni Yii

E ku deede iwoyii eyin ololufe wa, gege bee ti mo wi pe o ti to nnkan bi leta marun-un ti Morufa eko ti fi sowo si wa. Sugbon awon kan si n kowe ranse si wa wi pe awon ko ti ri awon leta kan ka ninu awon leta naa. Idi niyii ti mo fi ro wi pe o dara ki a ko awon leta naa jo si oju kan fun irorun awon oluka iroyin wa ti won tun je ololufe Morufa Eko. Titi di igba ti a o fi ri leta Eleekafa Morufa Eko gba, awon leta marun-un to ti ko siwaju ni yii:
Morufa Eko 1: "Mo Kabamo Wi Pe Mo Wa Si Ilu Eko" - Morufa

Morufa Eko 5: Ore Mi Ni Ki N Maa Fe Oko Anti Mi Sugbon Emi Fe Fun Ni
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment