Sii Olayemi Oniroyin,
Mo ki eyin oluka itan igbesi aye mi fun aduroti yin ati bi e se n ba mi fi okan baa awon alaye naa bo. Leta eleekesan-an ti maa fi ranse fun atejade ni yii.
Ma royin ki e se awari awon leta mi to ku lori ero ayelujara: E le te 'Morufa Eko' si ori ikanni google.com lati ka awon leta mi ateyin wa.
E je ki n tun gbe alaye mi nibi ti mo ba de…
A se ohun ti baba naa ni ka se. Baba naa ni ka pe oun ti a ba ti se tan, igba ti a setan, oko anti mi ke si i wi pe a ti se tan.
Baba naa wole pelu aso pupa, o ni ki n fi nu oju ara mi. Mo nu-un, mo si fi aso naa le e lowo pada. O ni ki n maa ti wo aso mi pada. Emi ati oko mi ti dide naro ni akoko yii.
O tun jade pada, o lo gbe ikoko dudu kan wa. Won da ina keke kan sinu ikoko naa, o si n se eefin jade. Eefin ti n jade ninu ikoko naa n run bi igba eniyan ba n sun ewe taba.
O gbe ikoko naa kale, o ni ki n ya ese mi mejeeji bi igba ti obirin ba fe to lori inaro, o gbe ikoko naa si mi labe. Ina naa n jo resuresu, sugbon oru ina naa jo mi nidi.
Oru ina to n jade si mi nidi ko koja ohun ti mo le mu mora. Igba to ti to nnkan bi iseju marun-un, aagun ti bo mi, o yi ti bere si ni ko mi.
Mo ti n gbon, bi eni to fe subu, mi o si mo ibi ti ara mi wa mo.
Sugbon nigba to ya, mo sakiyesi wi pe awon okunrin meji kan mu mi dani lotun ati losi, ikoko ti won gbe si abe mi kosi nibe mo.
Eje ti n jade lara mi, oko anti mi ti bere si mi labe, ori re si ni eje to n jade labe mi n dasi.
Babalawo naa n pe awon gbolohun kan bi ofo eleyii ti ko ye mi. Mo gbo awon oro enu baba naa bi eni wi pe ona jinjin lo ti n soro.
Eje n da ni ara mi, gbogbo ara oko anti mi si ti kun fun eje. Leyin eyi, mi o mo ohun to n sele mo, mi o si le so iru itu ti won fi mi pa.
E ku oju lona fun akotun leta mi ti n bo laipe. Ese.
Emi Ni Ti Yin Ni Tooto,
Morufa Eko

0 comments:
Post a Comment