Ni agbegbe Ikorodu to wa niluu Eko ni okunrin agbero kan ti bere si
ni wi kantankantan nibi o ti n pe awon ero soko. Awon eniyan ko tile
koko kaasi, a fi igba to bere si ni ja aso mo ara re lorun.
Awon eniyan to wa nitosi ni won sare kii mole ti won si gbe sinu moto ko to di wi pe yoo ja si aarin oja.
Gege bi iwadii iroyin se fi ye wa, oga omokunrin naa se alaye wi pe, igba akoko ko ni yii ti omokunrin agbero naa yoo maa se bi alaganna.

0 comments:
Post a Comment