Smiley face

Morufa Eko 8: Oko Anti Mi Mu Mi Lo Si Ile Babalawo; Ohun Oju Mi Ri Enu O Le Royin Tan

Sii Olayemi Oniroyin,

Oko anti mi si ti se ileri lati ba mi se oyun naa ni odo onisegun kan. Ojo ti a fe lo ti pe, o si ni ki n wa ogbon da ti maa fi kuro ni soobu anti mi lojo naa.

Mo paro fun anti mi wi pe inu n lo mi, mo si fe lo lo salanga nile. Sebi ile wa ko fi bee jina sibi ti a ti n taja ni oja Osodi. 


Mo lo pade oko anti mi nibi to ti ni ki n ti wa pade oun. Ilu Sagamu lo gbe mi lo. Kosi so fun mi titi taa fi de ibe wi pe Sagamu la n lo. 

Sugbon o fi mi lokan bale wi pe ko sewu, o ni ki n fi okan mi bale. Ibi ta a lo ki i se arin ilu bakan naa ni a ko le pe ibe ni igbo nitori awon ile wa nibe. 

Sugbon bi ile atijo ni gbogbo ile won, awon ile naa ko si sun mo ara won rara.
Ti eniyan ba de ile onisegun naa, eniyan o ti mo wi pe ile awo ni looto. Okan mi o bale, o si n semi bi ki n pada. Ibo ni mo fe sa pada lo? Se mo tile mona debi taa wa ka to wa wi pe ma mona dele?

Okan mi o se ohun ti mo fe se, o kan je wi pe ko wu mi lati ni iru oyun ti mo ni bakan naa. Kilode ti a o lo si osibitu, to fi wa je ile onisegun la wa? Se ori emi gan-an pe sa? 

Ara mi n gbon ninu, sugbon mi o je ko han nita. Ti mo ba fi eru tara pamo, se mo le mu eru kuro loju mi ni?.
Oko anti mi ri eru naa loju mi sugbon ko ye e so wi pe ki n fi okan mi bale. O ni ki n ma foya, ki n si ma sojo.

A joko die ki baba naa to yoju si mi. Awon omokunrin meji kan wole, won gbe ikoko dudu kan kale pelu adiye ibile meta, won tun pada jade pada nigba ti won ki wa ku ijoko tan. 

Awon mejeeji fi oruka ide si ika ese osi won to kere julo, pelu owo eyo ti won so mo orun owo osi. Awon mejeeji o wo aso sorun, sokoto ti won fi aso ofi se lo wa nidi okan nigba ti ekeji wo aso ankara to ti sa.
Awon mejeji ko ga ju ara won lo niwon ese bata marun-un o le die, won fari kodoro, ori naa si n dan bi eni wi pe won ti fi ororo paa. 

Won le je omo ikose-awo, won si le je omo baba ti a wa ba.

Ori aga gbooro ni emi ati oko anti mi joko si. Inu yara ti awa ni eniyan o ko ko kan ti eniyan ba wole, a le fi yara na we palo. Bi yara bi meta mii lo si tun jade si yara palo nibi taa joko si.

Ko to di wi pe awo inu ile, mo ri ile kekere kan lenu ona abawole legbe otun eleyi ti won ta mariwo si enu ona ile kekere naa.
Iyepe amo ni won fi ko ile naa, kini kan bi kukute ni won gbe sibe. Mo ri obi, epo pupa, ati awon nnkan mii ti mi o ri daada nitori wi pe mo wo firi lasan ni. 

Mo pada da ara mi lebi gan-an wi pe mo gboju lo si apa ona ibe. Ki oluware ma lo foju ko ohun ti ko ye o foju ko. 

Bi a se wole ni oko anti mi logun pe baba naa, "baba a ti de ooo."
Baba naa dahun lati inu ile," iwo ta nu-un o?" Oko anti mi daruko ara re. Baba ni ka joko wi pe oun ti n reti wa ati wi pe ise wa loun se lowo ninu ile. 

Ni enu ona abawo le nita, ohun ti won ko si enu ona ni yii:

"Oloye Akogun Aworemo Awoniyi (Akangbogbe Agbaye)".

Igba ti baba naa yoju sita, eniyan giga to lomi lara ni. Oun naa fari bi ti awon omo meji odo re ti mo ri saaju.
Ko wo ewu, ko wo sokoto, iro aso pupa nla kan lo ro mora. Ko tile beere ohunkohun lowo mi to fi gbe omi kan fun mi ninu igba, o ni ki n gba a ki n gbemu. 

Mo gba a, mo woju oko anti wo bi eni wi pe se ki n mu abi ki n ma mu, o foju ba mi soro wi pe ki n mu.
Mo koko fi ahon to omi naa wo bi mo se n sebi eni wi pe mo ti fe mu. Omi naa ni, ko ni iyato kankan lenu ju omi lo. Mo ba gbemu.

Igba ti mo mu tan, baba naa gba igba naa pada lowo mi. O pada sinu ile, o tun lo fi igba naa bu omi mii wa.
O gbe igba naa fun oko anti mi wi pe ki oun naa mu, owo kan ni oko anti mi da tie sofun.
Igba ti a se eleyii tan ni baba naa ni ka maa bo ninu yara kekere kan to wa lapa otun ibi taa joko si, eyi yato si yara ti baba naa ti lo n bu omi jade. 

Igba ti a wo yara naa, ko si ohunkohun ninu yara naa yato si apere kan ti won ko aso si to wa legbe ikangun yara.
Mo gbe oju mi woke, mo ri ado nla kan lenu ona abawole eleyii ti won fi iye yika pelu owo eyo.
Baba naa ni ki emi ati oko anti mi bo ara wa sile ni ihoho. O te aso dudu kan sile, o tun te pupa le e lori.
Igba to se eleyii tan. O ni ki awa mejeeji o kunle sori awon aso naa. O mu kini kan lubulubu jade bi eedu ti won ti lo. O da si mi lowo. 

O ni ki n da si aarin ori mi. Mo si se gele bo ti ni ki n se. O sin gbere meta siwaju ori mi, o mu eedu ti mo da si aarin ori, o fi pa oju gbere naa. 

O sin gbere meta siwaju oko anti mi naa, eedu aarin ori m naa lo fi pa oju gbere tie naa.
Igba to se gbogbo eleyii tan, O ni lara iranlowo ti oun fe se fun ni wi pe oko anti mi gbodo ba mi ni ajosepo lori awon aso ti oun te e le, o ni leyin eyi ni oun yoo se asekagba ti oyun yoo si jade ni irorun lai la mi loogun rara.

Baba naa jade sita, o wa ku emi ati oko anti mi ninu yara. O n semi bi ki n soro, sugbon mi o le soro.
Gbogbo ohun ti won ni ki n se ni mo n se. Oko anti mi feyin mi lele. 

O fi owo ko itan ese mi mejeeji soke bi igba ti awon olomolanke ba gba wibaaro lowo mu.
Sitori igbe aye mi si n tesiwaju. Mo ro yin ki e fi oju sona si leta mi tuntun to n bo lai pe.

Emi Ni Tiyin Ni Tooto,
Morufa Eko
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment