Aare ilu Burundi, Pierre Nkurunziza ti wole gege bi aare ilu naa fun igba keta tele ra. Iru aba yii naa ni Aare ile Nigeria nigba kan ri, Olusegun Obasanjo da sugbon ti aba naa ko jo.
Bi o tile je wi pe aimoye rugudu ati itaje sile lo waye saaju eto idibo to waye lojo isegun to koja yii, lopin ohun gbogbo, ibo Aare Pierre Nkurunziza kun to nnkan bi ida aadorin (70%) eleyii to mu leke to si mu wole gege bi aare fun igba keta.
Nibayii, awon egbe alatako ilu naa ti koyin si esi idibo naa, won ni bi Aare Pierre Nkurunziza se dije fun igba keta lodi si iwe ofin ilu naa.

0 comments:
Post a Comment