Smiley face

Aderupoko ati Papalolo Wa Si Ori Eto Kola Olootu

Otunba Kola Olootu gbalejo Ayo Ogunshina (Papalolo) ati Kayode Olaiya (Aderupoko) loni lori eto re, Oselenkejo lori redio Oluyole FM to wa ni ilu Ibadan.

Kayode Olaiya yii kan naa lo kopa Sajenti Sunday Afonja ninu fiimu tuntun "October 1st" ti Kunle Afolayan se.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment