Iyawo ogbontarigi onise tiata, Emeka Ike ti lo si ile ejo lati be adajo wi pe ko tu yigi to wa laaarin oun ati oko re ka.
Ese Igbeyawo odun mejila ti bere si ni mi bayii ti enikeni ko si mo ibi ti oro naa yo yori si. Lowolowo bayii, toko-taya naa ko gbe papo mo; eleyii si ti se die.
Lara esun ti iyawo re fi kan an naa ni lilu ti oko re maa n na bi igba eniyan n lu bara.
Tuntun ti a tun gbo wi pe Emeka ti ko eyin awon omo re si iya won. Awon omo gan-an won ko fe ri iya won mo. Won ni ko bikita, ko si naani awon gege bi omo re.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment