Obo langido kan to wo agbegbe Oru to wa ni Ago Iwoye, Ipinle Ogun ti
koja lo sorun laaaro yii lowo bajinatu okan ninu awon olode agbegbe naa.
Won ni lana ni won kofiri obo naa eleyii ti n je awon eniyan lounje to si n seku pa awon ohun osin won.
Sugbon sa, laaaro yii ni owo palanba re segi, ti iku ojiji si mu lo si ajule orun nigba ti ode fi ibon fo o latari danu. Ti atari re si fo yanga-yanga sile bi keregbe to jabo fo pelu omi ninu.
Ninu iroyin mii, nje e ti gbo wi pe awon senato kan ti n mura lati yo olori ile igbimo asofin agba, Bukola Saraki, loye to ba di ose to n bo nigba ti ile yoo maa pade?
Yato si eleyii, ile ise ijoba apapo tun ti gbe sita wi pe ile ise epo robi, NNPC ile Nigeria ti pinyinkin fun iwa jegudujera.
Bakan naa, Aare Muhammadu Buhari wi pe won ti gbe si oun leti nipa oruko tuntun ti awon omo Nigeria fi da oun lola. Oruko tuntun naa ni "Baba Go Slow".
Nje oruko yii ye SaiBaaba bi?
Kilode ti awon omo naija fi seda oruko naa fun-un?
Mo n fi asiko yii ki Gbenga Olokede gege bo ti jawe olubori gege bi alaga egbe akoroyin ti eka ile ise BCOS to wa ni ilu Ibadan. Asiko re yoo tura o! Amin
Ibi yii ni maa ti duro.
E ku faaji!

0 comments:
Post a Comment