ÀWON ÒWE IḶẸ̀ YORÙBÁ (PROVERBS OF THE YORUBA PEOPLE)
Ilé oba tójó, ewà ló bù kun.(If you fail once,try again,failure is the preparation of greater things ahead).
Igi gogoro má gun mi lójú, à t'òkèrè latí wòó.(Be conscious of your actions)
Bá mi na omo mìi, kò dénu olómo.(Oftentimes people say what they do not mean so thread softly)
A kìí bá ara eni tan kí á fara eni nítan ya.(When you are given an opportunity, don't misuse or overuse it)
Àgbà kìí wà lójà, k'órí omo tuntun ó wó.(Where there are elders, things are run smoothly).
Orí tí yóó gbeni ní gbé aláwo 're ko ni.(Your destiny is in your hands)
Eni tí n korin tí kò dùn, o ṣaa n feti ara e gbo o.
Àgbà tí ò bínú ni ọmọ rè n pò jọjọ. (Be slow to anger)
Kí Ọbìnrin to àtòrìn, Kí Ọkùnrin to àtòrìn,ká wo ẹni tí ó lómi léyìn ẹsẹ̀ ju ara won lo.
Apé kó tó jeun, kò ní jè bàjé.(Delay is not denial).
Àṣegbé kankan ò sí,àṣepamó lówà.
Bí iró bá lo lógún odún,òtító á padà lé bá.
Iyán ogún odún, a máa jó ni lówó felifeli.
Káronú jinlè ká tó wùwà lódaa, ìwà òpònú ni ká se nnkan òún tán,káwá dorí kodò lórí àṣise.
Bi Ina njo ni jo omo eni tara eni laa ko gbon.
Ori yeye ni mogun, t'aise lo po.
A kini unje akini afinihan unje afinihan e wo ni pele ara Ibadan lojude Ogunmola.
Àifète m'éte, àìfèrò m'erò, ọmọ iya mẹfa kú si oko ẹgbàafà.
A kò fẹ́ ọ ni ilu, o ni iwọ yio da orin, bi o ba dá orin nà, tani yio ba ọ gbè é?

0 comments:
Post a Comment