Tajudeen Azeez omo odun merindinlogun(16) ni owo awon olopa ti te
pelu bo se seku pa Ibrahim, omo odun merin (4) kan ni agbegbe Ijanikin
to wa ni ipinle Eko.
Gege bi a se gbo, Azeez yo kidirin ati ifun omo naa kale leyin igba to seku paa tan.
Awon kan ni won be Azeez ni ise buruku yii pelu adehun wipe won yoo fun ni egberun lona aadota owo naira (50k) ti o ba le ba won se awari awon eya ara eniyan kan.
Igba ti n se ise ibi yii lowo ni awon kan kofiri Azeez ninu ile iwe Anglican Primary School, Ijanikin nibi to dogbon tan omo naa lo ko to di wi pe o seku pa ni ipakupa nitori egberun lona aadota owo naira.
Sugbon ki awon olopa to de agbegbe naa, eya ara Ibrahim ti ge kelekele sile bi igba awon alapata saayan eran kale fun tita.
Won ti gbe oku omo naa si ile igbokusi nigba ti won fi Azeez pamo si gbaga awon olopa titi won yoo fi se idajo re bo ti to ati bo ti ye.

0 comments:
Post a Comment