Awon Yoruba bo, won ni inu eni kii dun ka pa mora.
Ki lo dun bi ki obi fi owo ribiribi ran omo re ni ile iwe ki omo naa si kawe yege? Idunnu bii re ko legbe.
Foto yii lo ti n ja rainrain lori ayelukara eleyii to n se afihan baba to fi owo ran awon omo re obirin meji ni ile iwe loke okun ti awon omo naa si kawe yege.
Inu baba dun ladun ju, swagger ni baba fi n ya foto pelu awon omo re.
Adura mi ni wi pe, a ko ni ribanuje lojo ayo wa. Isu omo yoo jina fun gbogbo wa. Amin
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment