Leyin ejo ti awon omo ile igbimo asofin agba kan te pepe re si iwaju ile ejo to gaju lo ni ilu Abuja nipa esun wi pe Bukola Saraki ati igbakeji re ledi apo po mo awon kan lati yi ofin ilana ati agbekale ile igbimo ni ile ejo ti ko danu bayii.
Awon senato ti won sare gbe ejo naa lo si ile ejo ni Senato Abu Ibrahim, Kabir Marafa, Ajayi Boroffice, Olugbenga Ashafa ati Suleiman Hunkuni.
Sugbon gege bi onidajo Gabriel Kolawole
Se so, o ni esun won ko duro lori ododo bi ko se etaanu,tembelekun ati rikisi.
Sodiafo, Onidajo Gabriel Kolawole ba fa iwe ejo naa ya, o ni ko soro nibe rara.
0 comments:
Post a Comment