Ni aye igba kan, ti won ba n so nipa iroyin ado-oloro, o ni lati je awon ilu okeere. Sugbon nile toni to mo, joojumo ni iroyin ado oloro to dun ni ile wa n jade.
Alafia ti salo ni awon agbegbe kan, inu iberubojo ni awon kan an gbe igbesi aye won.
Edumare nikan lo si le ran wa lowo nibi ti oro de bayii. Ki ogo ile wa ma parun tan lowo awon ika eniyan.
Alaye foto: Awon osise alaabo n ye omo kekere wo boya ado-oloro bombu mbe labe aso re ni agbegbe ti awon eniyan ti n pejo lati kirun odun itunu awe.
Aanu re la n beere Oluwa. Gba wa lowo awon ika eniyan, ki o si da ogo ile wa pada pelu alaafia to peye. Amin
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment