Ijamba Oko: Oko Ajagbe Jabo Lati Ori Afara Niluu Pota Ola Daviva 8/22/2015 01:58:00 pm Iroyin , Yoruba Edit Ni aaro yii ni oko ajagbe kan jabo lule bi igba ti won ba ju apo ewa lule lati ori afara to wa ni ikorita Rumoula to wa niluu Pota ni Ipinle Rivers. Emi kankan ko ba isele naa lo. Share on Facebook Share on Twitter Share on Google Plus About Ola Daviva RELATED POSTS Ijamba Oko: Oko Ajagbe Jabo Lati Ori Afara Niluu Pota Reviewed by Ola Daviva on 8/22/2015 01:58:00 pm Rating: 5
0 comments:
Post a Comment