Sebi asa tuntun nibi igbeyawo aye ode
oni ni ki iyawo ju ododo igbeyawo re si awon ore re. Enikeni to ba mu
ododo naa nigba ti iyawo ba juu si awon ore re ni awon eniyan yoo gba wi
pe oun lo kan lati se igbeyawo.
Ohun to un sele gan-an niyii ninu aworan oke yii.
Aso penpe ti o bodi tan lomobirin naa wo, igba ti iyawo o ju ododo owo re ti gbogbo awon ore o si fo soke lati mu u ni asiri omobirin naa ba tu.
E le biliifu wi pe omoge naa o wo pata sidi. Bo se fo soke bayii ni iyamopo re fo jade lau labe aso. Gbogbo ohun ti n be labe aso wa di fiimu fun gbogbo awon alejo ti won wa sibi eto igbeyawo naa.
Oju gba mi ti fomoge;
Oju gba mi ti fun orekelewa ti o lojuti;
Oju gba mi ti fun opo awon ewe ti olaju ti so di were lawujo.
Olayemi ni oruko mi, e si tun le pe mi Agbasaga Gbogbo Ile Adulawo Pata.
E ku ikale!
0 comments:
Post a Comment