Awon Yoruba bo, won ni baa se beru la bomo. Ona lo jin, eru ni baba. Iroyin ti gba igboro bayii nipa omokunrin ti n sise gege bi omoodo ni agbegbe Gemade to wa ni Ipinle Eko eleyii ti madaamu re da omi gbigbona si lara.
Omokunrin naa ti n gba itoju ni ile iwosan bayii nigba ti awon agbofinro ti so madaamu to je oga omo naa si gbaga.
Ti awon ojulowo omo Yoruba pombele ba fe soro, won a ni ki o to fi ina jo omoolomo, gbiyanju ko fi jo ara re na ko le mo bi ti n ri lara.
E je ka se rere!
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment