Yoruba loni, otin kii pago, eni o ba motin lotin n pa. Ni oju ona Ife atijo to wa ni ilu Ibadan ni iroyin so nipa okan lara awon olopa ti mo n dari oko oju popona ti gbe mu otin yo keri ni nnkan bi ago mejila osan ana (6-8-15).
Awon ti won mo okunrin naa tile so wi pe ikorita Onipepeye ni okunrin naa ma n duro si dari awon oko ti n lo ti n bo.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment