Awon Yoruba ni eni ti yoo daso fun ni, torun re la a wo. Lai pe yii ni iroyin kan jade nipa oga yelofifa to mu otin yo ni ilu Ibadan nile Oluyole.
Ti olopa yelofifa ba mu otin yo, sebi ko sun soju popo lasan ni yoo gbeyin oro re.
Sugbon ewu nla ni ti olopa agbofinro onibajinatu lowo ba mu burukutu yo. Ti jagunlabi ba mu o tin yo tan, o ma le se bee paayan ke?
Oro yii n fe amojuto gidi gan-an o.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment