Yeye Lua gbogbo awon onise nabi ile Naijeria, Cossy Orjiakor ti bere si ni gbe igba ope latari eru aya erimo ti Olorun oba fi daa lola. Oro yii lo jade lori ikanni Facebook re, ohun to so ni yii:
"Mo dupe fun Olorun fun oke ribiti to gbe si mi laya. Bi o tile je wi pe won maa n dabi eru fun mi lekookan sibesibe inu mi dun si bo se ri gelete"
Bakan naa, laipe yii ni omobirin naa tun so fun awon oniwe iroyin Vanguard ti ile Nigeria wi pe, oyan aya oun kii se ounje fun awon omo oun rara.
" Nnkan bi odun mewaa si igba taa wayii, awon oyan aya mi yoo si duro soke sibe nitori wi pe mi o ni fun omokankan laaye lati mu oyan aya mi. N maa ba won fi nnkan fa omi oyan naa jade sinu koopu fun won ni."
0 comments:
Post a Comment