Smiley face

Asiri Bobo Ti Won Pe Ni Don Jazzy Pada Tu Si Mi Lowo: Alagbari Ni Maanu Na

Haa! Eniyan buru sa. Abalajo ti maanu naa ko se kobiara sohun to ba jo mo igbeyawo.

Bi o tile je wi pe, won ni eni ti o ba se igbeyawo yoo se "gudugudu meje."

Sugbon iru gudugudu meje wo ni Don
Janzz fe se ti ko le se?

Owo wa, okiki wa, o rewa lokunrin, o tun gbayi repete. Bobo naa tun lenu pon pon pon bi Oba Lamidi.

Gbogbo igba lo maa n so wi pe oun o ti redi lati se igbeyawo, a se jagunlabi ti jegboro tan ni.

Gege bi atejade kan eleyii to lu si Olayemi Oniroyin lowo, nibe ni Don Jazzy tun ti so wi pe oro igbeyawo ko si ninu ajenda oun rara.

Igba ti won tun bi alase ile ise orin Mavin wi pe se lotito ni iroyin to jade nipa wi pe o ti bimo sita.

Agbari ni ogbeni Collins fi dahun ibeere yii:

Olayeni Oniroyin: Nje e ni omo sita gege bi iroyin to jade se so?

Don Jazz: "Emi o mo boya mo lomo kankan nibi kan o. Enikan le wa ko ni mo ni omo okunrin omo odun mesan-an kan, a si lo se ayewo eje, mo si ri pe temi ni."

Haa! Okunrin! Olorun lo moye omo to ti bi kaakiri baun. Ni o si mo 'piritendi' fawa bi eni wi pe 'fada' ti kii sun mo obirin ni

Eniwee, laipe, awon asiri to ku ko ni pe lu si mi lowo.

Eyin e saa ma te le mi lori twitter, @OlayemiOniroyin loju opo mi.

E se gan-an
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment