Smiley face

Awon 'Omo Aye' Ti Gba Ibon Lowo Olopaa To Moti Yo Nile Asewo

Okunrin olopaa to lo mu oti yo ni yii nile asewo kan to wa ni agbegbe Ikeja niluu Eko. Igba to mu oti yo ni awon omo igboro ji ibon re mo o lowo. Ogbeni olopaa naa ti wa ninu ahamo awon olopaa bayii.

Ojuti nla leyii je fun ile ise olopaa ile Niajeria.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment