Smiley face

Baba Suwe Ti Ni Iyawo Tuntun Leyin Iku Omoladun: Won O Se Igbeyawo Laipe

Leyin gbogbo fitinati ti ajo NDLEA fi oju Babatunde Omidina ri pelu esun wi pe osere alawada naa gbe ogun oloro mi sikun ati bi Adimeru se padanu ololufe re, Omoladun; irawo osere onitiata naa ti kede wi pe oun ko ni pe se igbeyawo tuntun pelu obirin mi-in.

O salaye wi pe iku Omoladun dun oun gidi, kosi si obirin to le dabi re ninu igbe aye oun mo. Sugbon o didan fun oun lati tesiwaju igbe aye oun leyin iku Omoladun.

Tani ni obirin ti Baba Suwe fe fi saya?

O ni obirin naa kii se osere sinima, laipe, ti akoko ba to gbogbo oju ni yoo ri.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment