Gbajumo oserebirin ilu Ghana Rose Mensah, eleyii ti gbogbo eniyan mo si
Kyeiwaa, lo se igbeyawo alarede alarinrin pelu okunrin onisowo kan ti n gbe ni Kumasi to wa ni orileede Ghana bakan naa.
Sugbon ohun to jo ni loju ni wi pe oserebirin naa ko oko re, aniel Osei sile leyin ojo kerin ti won se igbeyawo aladun naa.
Ki lo de ti oserebirin naa fi ko oko re sile?
Gege bi ohun ti a gbo, ojo keji leyin igbeyawo won ni asiri okunrin naa tu si Kyeiwaa lowo wi pe okunrin naa ti niyawo sile pelu omo merin.
Ati wi pe gbogbo awon alejo ati ebi ti maanu naa ko wa sibi eto igbeyawo lo je awon eniyan to lo fi owo haya, won kii se awon eniyan re rara.
Se eyin naa ri wi pe okunrin ko le rorun wo?
0 comments:
Post a Comment