Amunibuni bi eran Ibiye ni bobo ti won pe ni Yusuf Ayofe yii. Ki lo wa de odo Kemi Omololu-Olunloyo, omo gomina Ipinle Oyo nigba kan ri? Gbogbo eniyan lo ti mo "logo" re, won maa n yago fun ni ti won ba pade re nibikibi.
Aifarabale Mista Yusuf Ayofe ti je ki omobirin naa tun soro kobakungbe ranse si gbogbo omo Yoruba pata.
Ohun ti Kemi Omololu-Olunloyo gbe jade re e lori Facebook nibi to ti n se afihan geesi ogbeni Yusuf gege bi agbekale ti ko gun rege eleyii to se apeere bobo naa gege bi eni ti ede geesi re nisoro die:
"ANOTHER REASON WHY YORUBAS ARE THE WORST ILLITERATES ONLINE AND OFFLINE!
'Yusuf Ayofe Dr, Madam, Pharm KOO, you said you have never been married but you have children. It means you are a divorcee
Like · Reply · 6 mins'
Dr Kemi Omololu-Olunloyo OMG!! The level of illiteracy on my page is so sad. You are a solid certified illiterate. A divorcee is a woman that got married and DIVORCED! Im not a divorcee. Im a single mom. Shame on the low class mentality here. Pls go back to school".
http://www.merriam-webster.com/dictionary/divorc%C3%A9e
http://m.facebook.com/l.php?u=http%3A%2F%2Fwww.merriam-webster.com%2Fdictionary%2Fdivorc%25C3%25A9e&h=JAQFmOwtX&s=1
0 comments:
Post a Comment