Iwe "Iroyin Owuro" ose yii tun ti jade. Awon iroyin inu re ngbona felifeli.
Die ni yii ninu awon koko iroyin to jade:
*Buhari da nnkan ru mo awon oloye egbe APC loju
*"Babalawo ko ni lo si paradise" - Oloye Ademola Fabunmi
*Femi Adesinia: Oloore Ibafo dero Abuja
*Ayefele da ile ise redio sile
* Asakasa, asa gay
E gbiyanju ki e ra iwe Iroyin Owuro lati je igbadun awon koko iroyin yii ati awon iroyin gbankogbi mi-in.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment