Odun 2014 ni magasininni Forbes agbaye se afihan Oba Fredrick Obateru Akinruntan gege bi oba ti iye dukia re to oodunrun milionu owo ile Amerika ($300 million).
Eleyii to mu je ori ade to ni owo julo ni ile Nigeria.
Ugbo ti oba yii n se alakoso le lori wa ni ijoba ibile Ilaje ni ipinle Ondo.
Nipa ti Akolawole Olootu: Kola Olootu je okan lara awon sorosoro ede Yoruba onirawo meje ni ile Nigeria ati loke okun.
Emi ko ni mo fun Kola Olootu nirawo meje, ohun to wa lapa Olootu ni mo so diroyin akede.
Awon kan tile so wi pe to ba je wi pe orin juju kiko nise re, o daju wi pe Sunny Ade ni o ba je. Sugbon Olootu kii korin, sorosoro to gbayi ni.
Won tun ni to ba je wi pe alawada kerikeri tun ni nko? Won ni o seese ko pada je Alibaba ti n gba milionu bi meji abo ko to di wi pe yoo pa awon eniyan lerin. Sugbon Omo Adabanija kii se alawada, ogbontarigi sorosoro to mo ayinike ati ayinipada ise ti n se ni.
Igba ti awon omo adamo tun fe fi sugar si fanta, won ni to ba je wi pe Banki ni Kola Olootu nko? Awon kan ni Zenith ni o seese ko je tabi First banki. Sugbon Olootu kii se banki, sorosoro to pawo ti ori re si pe bi alajosomolu ni.
Sugbon emi mo ninu okan mi wi pe to ba je pe goofu ni Olootu n gba ni, Tiger Wood ni o ba je.
Lara akiyesi mi ni awon igba kan seyin: Mo sakiyesi wi pe Otunba Kola Olootu ni "enu bode" ti awon oloja ti won ba fe polowo oja won niluu Ibadan n gba wole. Eni ti o ba si gba enu bode wole, ilu Ibadan ko le mo iru oja ti eni naa n ta.
To ba jo bi iro, Oluyole ni ke ti lo beere oro.
Olayemi Oniroyin, maa duro nibi na ki promo yen ma lo poju. Sugbon fun awon iroyin mii to jo iru eleyii, maa ro yin ki e se ayewo awon linki isale yii.
E ku faaji!
Awon Oba Alaye Marun-un To Lowo Ju Ni Ile Afirika
www.olayemioniroyin.com/2014/06/awon-oba-alaye-marun-un-to-lowo-ju-ni.html?m=1
www.olayemioniroyin.com/2014/06/awon-oba-alaye-marun-un-to-lowo-ju-ni.html?m=1
Ohun Ti E Ko Mo Nipa Kola Olootu Omo Adabanija
www.olayemioniroyin.com/2014/11/ohun-ti-e-ko-mo-nipa-kola-olootu-omo.html?m=1
www.olayemioniroyin.com/2014/11/ohun-ti-e-ko-mo-nipa-kola-olootu-omo.html?m=1
Aderupoko ati Papalolo Wa Si Ori Eto Kola Olootu
www.olayemioniroyin.com/2015/07/aderupoko-ati-papalolo-wa-si-ori-eto.html?m=1
Kola Olootu Lagbade Fun
www.olayemioniroyin.com/2014/10/kola-olootu-lagbade-fun.html?m=1
www.olayemioniroyin.com/2014/10/kola-olootu-lagbade-fun.html?m=1
Kola Olootu Ti Mura Tan Lati Lo Si Pati Femi Solar
www.olayemioniroyin.com/2014/05/kola-olootu-ti-mura-tan-lati-lo-si-pati.html?m=1
Ojogbon Wande Abimbola Lori Eto Kola Olootu
www.olayemioniroyin.com/2013/09/ojogbon-wande-abimbola-lori-eto-kola.html?m=1
www.olayemioniroyin.com/2013/09/ojogbon-wande-abimbola-lori-eto-kola.html?m=1
Aworan Kola Olootu Ati Oga Nla Fuji
www.olayemioniroyin.com/2013/08/aworan-kola-olootu-ati-oga-nla-fuji.html?m=1
Kini Kola Olootu Fe Se To pe Osupa Ati Oga Nla Papo Lojo Kan Soso?
www.olayemioniroyin.com/2014/04/kini-kola-olootu-fe-se-to-pe-osupa-ati.html?m=1
www.olayemioniroyin.com/2014/04/kini-kola-olootu-fe-se-to-pe-osupa-ati.html?m=1
0 comments:
Post a Comment