Ti Yoruba ba fe soro, won a ni bee merin sebi e gbohun erin. Bee mosa sebi gbogbo wa la jiyo lobe. Bi enikan ba ni oun o mo Uncle Wemi, se o le tun ni oun mo ALE ARIWO, TIM BA T'AIYE WA, KODUN KOPO KOPE(KKK), OYATO, AYE JOBELE, KOSORUGUN (No Rival) ati ARA?
Fiimu Wemimo Olu Paul, AKUNLEYAN, je fiimu eleeketa ninu awon fiimu agbelewo akoko ti yoo jade ni gbogbo ile Naijeria pata.
Fiimu agbelewo akoko ni EKUN eleyii ti Alade Aromire se. Eleekeji ni IGI DA lati owo Latunde Films nigba ti AKUNLEYAN je eleeketa lati owo Uncle Wemi.
Oni ojo ibi Wemimo Olu Paul, adura wa ni alaafia to peye, ifokanbale ati emi gigun fun akoni to le lodun lonii. Igba odun, odun kan ni. Amin
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment