Smiley face

Odaju Abiyamo Fi Ina Jo Omobirin Eni Odun Merindinlogun Loju Ara: O Ni Omo Naa N Se Agbere

Omobirin odaran kan ni owo awon olopaa ti te ni agbegbe Ketu niluu Eko pelu bo se fi ero ayoonu iloso jo omo egbon re ti n gbe pelu re, Bimpe Badmus, omo odun merindinlogun, nidi pelu esun wi pe omobirin naa n ba omo lanloodu won lajosepo.

Isele to sele ni opopona Ogunjimi ni obirin naa ti fi ayoonu iloso jo Bimpe loju ara, ikun ati itan omo naa pelu iranlowo awon awon ore meji kan ti won ba a mu omo naa duro.

Gbogbo awon onise ibi naa ni won ti wa ni gbaga awon olopaa bayii nibi ti won ti n jo "azonto" nigba ti Bimpe wa ni osibitu.

Lara oro Bimpe, "Iro ni gbogbo oro naa, ko si nnkankan laaarin emi ati omo lanloodu."
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment