Ewi: E ma ya baseje
Eyin ewe
iwoyii, e wa teti si agogo ogbon
E ma ya
baseje
Baseje ti n
bale je ni won pe larungun
Arungun ni
eni ti n ba ohun ti won fowo se je
Oninakuna
omode ni won pe lapa.
E ma ya
baseje
E ma ba ohun
ti won fowo ra je.
To ba je omo
ile iwe toju iwe re daada
To ba wa
nile ma ba ohun iya ati baba fowo ra je
Ibikibi too
ba de, toju ohun gbogbo ti nbe layika re
Ti won ba
fun o lowo ma nanakuna
Oninakuna
won ki i rowo se ohun rere laye
Omode to ba
yapa won ki i ni laari bo dola.
E ma ya baseje
Eniyan to ba
ba ohun ti won fowo se je kii niyi.
0 comments:
Post a Comment