Smiley face

Ninu Iroyin Owuro ose yii: Okunrin kan ko N2M owo ifeyinti re fun pasito ni Mowe, loro ba di gobe

Ninu Iroyin Owuro ose yii: Okunrin kan ko N2M owo ifeyinti re fun pasito ni Mowe, loro ba di gobe

Iroyin Owuro ose yii tun ti gori igba. Iwe iroyin ti n gbona felifeli. Die ni yii ninu awon koko iroyin ose yii



* Ireti ati di minisita: Aregbesola re Oyinlola lepa

*Arekenge! Osinbajo ati aya re fife han nita gbangba

*Kayeefi! Omo tuntun gbe Bibeli waye ni Ila Orogun

*Ni Mowe, okunrin kan ko N2M owo ifeyinti re fun pasito

*Oba Deji Akure fi ibinu gbade lori oba Ibo

*Awon olopaa ti lo ko awon omo egbe okunkun n'Ijebu Ode

*Fayose kede nomba ero ibanisoro re fun awon eniyan ipinle Ekiti

*Abiyamo gbe omo re ta nitori owo

*Awon ota ko deyin leyin Ameachi

*Ayeye ojo ibi Alaafin Oyo: Oba Lamidi pe eni odun metadinlogorin

Ogorun naira pere ni Iroyin Owuro. E ri daju wi pe e beere lowo fendo yin. Aseti kii bojo, aseti kii boorun, aseti ko ni bayin laelae. Amin

http://www.facebook.com/photo.php?fbid=903617199724164&set=gm.1069515686433073&type=3
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment