Mo ri okunrin aro kan ti ko lapa kan lori afara ti awon elese n gba soda niluu Eko. Okunrin naa n fi igbale gba gbogbo ori afara laise wi pe enikeni gbese naa fun. Isesi okunrin naa wu mi lori, mo si sun moo lati foro wa lenu wo. ori re ko daru, eniyan tori re pe ni. Laipe, n maa salaye ohun ti mo mubo.
Sugbon ohun kan lo damiloju, iye awon eniyan ti won ba Naijiria je le po, sugbon awon olododo eniyan kan si wa ti won tun un se pelu inu kan.
Olayemi Oniroyin ni oruko mi, e ku ikale!
Sugbon ohun kan lo damiloju, iye awon eniyan ti won ba Naijiria je le po, sugbon awon olododo eniyan kan si wa ti won tun un se pelu inu kan.
Olayemi Oniroyin ni oruko mi, e ku ikale!
0 comments:
Post a Comment