Smiley face

Iru iku wo lo pa Kofeso Ogunniyi ni OAU ti Ile-Ife?

Solomon Ogunniyi
Ojogbon Solomon Ogunniyi, eni ogota odun, ti ile iwe Obafemi Awolowo University to kale siluu ile ife ni won sadeede ba oku re ninu ofiisi re to wa ninu ogba ileewe naa l'Ojobo to koja yii lai mo ibi ti iku naa gba wole.



Kofeso Ogunniyi, ojogbon onimo ijinle nipa isegun oyinbo ni won fura wi pe ko jada sita ni ofiisi re fun igba pipe, eleyii to si mu awon kan lo se abewo sii.

Sugbon nigba ti won yoo debe, oku re ni won ba lori aga re nibi to joko si.

Iku re naa mu ifura dani, awon eniyan si ti beere si ni so awon ohun to seese ko sokunfa iku oga agba fun eka ti won ti ko nipa sayensi ilera ti ile eko naa nigba kan ri.

Sugbon gbogbo aheso to n jade nipa iku oluko naa, ko si eyi to ti fidi mule nigba ti iwadii si n lo lowo nipa ohun to fa isele buruku naa.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment