Smiley face

Se aso oge naa ni yii?

Kini a le pe iru aso oge bayii? Se were alaso ni abi were alakisa? Pelu bi nnkan se n lo, se e lero wi pe to ba ya, awon eniyan ko ni ma wo pata lasan rin nigboro. A fi ki Jesu yaa tete de o. Nitori a ko le maa ba bayii lo.

E le ka ero awon eniyan NIBI:
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment