Lati
ana ni awuyewuye naa ti n ja raintain nile nigba ti Davido ati ebi re
fe gbe omo to wa laaarin Davido ati Sophie to je afesona Davido nigba
kan rin irinajo leyin iya omo naa. Iya omo naa, Sophie, lo je bi aburo
si Dele Momodu, eni to fi oro naa to awon eso oju ona ti n risi wole
wode leti wi pe Davido fe ji omo naa gbe salo ni. Alaye awon mejeeji ni
yii.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment