Awon arije ni madaru, ika, odaju, ole, wobia, wonbiliki le po ni
Naijiria loooto, sugbon awon eniyan rere ko ti tan lawujo wa. Okan
ninu won ni alase ile epo Bovas to kale silu Ibadan. Bakan naa ni awon eniyan jeri si wi pe, won ko fi owo kun owo epo won ni awon eka ile ise won to wa kaakiri ile Naijiria.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment