Ìtọ̀
idi iya ọmọ naa la maa kan diẹ si lẹnu, oju ati furọ ọmọ naa. Bakan naa ni a ma
fi itọ naa pa gbogbo omo naa lara. Ti a ba se eleyii, giri naa yoo salọ ni
aṣẹ Oluwa.
Ona
keji ti a tun le gba se iwasan fun omo to ba ni giri ni yii.
A
ma lo alubosa gidi, alubosa ayu ati ginger papọ mọ ara won. Leyin eyi, a ma wa
da papọ mọ epo pupa. A ma wa fi pa gbogbo ara omo naa, titi to fi mọ oju ati ẹnu
omo naa.
Ti a ba se eleyii, giri naa yoo fi omo naa silẹ lọwọ kan pẹlu ase
Eledumare.
Olayemi Oniroyin kii se onisegun, iwadii lasan ni mo se lọwọ awon agba. Edumare
to jẹ oluwosan, yo mu gbogbo wa lara da.
Enter your comment...ESE pupo olorun yio ma ran yi lowo esini se aseti lagbara olorun motira Ogun laimoye igba fun omo yi sibesibe aisan giri yi kolo oruko Ogun timo nra fun ni tregtor tablet ti won ko fun wa ni
ReplyDeleteuch hospital