Mi o so wi pe ki enikeni ma se atunte awon iroyin tabi apileko mi lori Olayemi Oniroyin. Sugbon enikeni to ba se bee gbodo se ohun to ye nipa sise afihan orisun ibi ti won ti gbe ri awon iroyin tabi apileko naa ti won gbe si ori ate ti won. ( Eleyii ti kii se ise opolo ti won gan-angan)
Eni to ji mi laso ko rohun ji, bi eniyan ba ji mi lewu kii dun mi taara. Eni jale ise opolo lo se mi nijamba.
#kilokilo
Olayemi Olatilewa
(Olayemi Oniroyin)
0 comments:
Post a Comment